1 Jòhánù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwá mọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí a bí nípa ti Ọlọ́run kì í dẹ́ṣẹ̀: ṣùgbọ́n ẹni tí a bí nípa tí Ọlọ́run a pá ara rẹ̀ mọ́, ẹni búburú kò ní lè fọwọ kàn án.

1 Jòhánù 5

1 Jòhánù 5:12-21