1 Jòhánù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa èyí ni a gbé fi ìfẹ́ Ọlọ́run hàn nínú wa, nítorí tí Ọlọ́run rán ọmọ bíbí rẹ̀ nìkan ṣoṣo sì ayé, kí àwa lè yè nípasẹ̀ rẹ̀.

1 Jòhánù 4

1 Jòhánù 4:1-13