1 Jòhánù 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ayé ni wọ́n, nítorí náà ni wọn ṣe ń sọ̀rọ̀ bí ẹni ti ayé, ayé sì ń gbọ́ tí wọn.

1 Jòhánù 4

1 Jòhánù 4:4-9