1 Jòhánù 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú èyí ni a mú ìfẹ́ tí ó wà nínú wa pé, kí àwa bà á lè ni ìgboyà ní ọjọ́ ìdájọ́: nítorí pé bí òun tí rí, bẹ́ẹ̀ ni àwa sì rí ni ayé yìí.

1 Jòhánù 4

1 Jòhánù 4:14-20