1 Jòhánù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa èyí ni àwa mọ ìfẹ́ nítorí tí ó fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ fún wa: ó sì yẹ kí àwa fi ẹ̀mí wa lélẹ̀ fún àwọn ará.

1 Jòhánù 3

1 Jòhánù 3:6-23