1 Jòhánù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú èyí ni àwọn ọmọ Ọlọ́run ń farahàn, àti àwọn ọmọ Èṣù; ẹníkẹni í kò ba ń ṣe òdodo, àti ẹni tí kò fẹ́ràn arákùnrin rẹ̀ kì í ṣe ti Ọlọ́run.

1 Jòhánù 3

1 Jòhánù 3:1-13