1 Jòhánù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí o bá sì wí pé òun ń wà nínú ìmọ́lẹ̀, tí o sì kóríra arákùnrin rẹ̀ sì ń bẹ nínú òkùnkùn.

1 Jòhánù 2

1 Jòhánù 2:4-13