1 Jòhánù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó bá wí pé, “Èmi mọ̀ ọ́n,” tí kò sì pa òfin rẹ̀ mọ́, èké ni, òtítọ́ kò sì sí nínú rẹ̀.

1 Jòhánù 2

1 Jòhánù 2:1-6