1 Jòhánù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ́ kí èyí tí ẹ tí gbọ́ ni àtètèkọ́ṣe máa gbé inú yín. Bí èyí tí ẹ̀yin tí gbọ́ ní àtètèkọ́ṣe bá ń gbé inú yín, ẹ̀yin ó sì dúró nínú Ọmọ àti nínú Baba.

1 Jòhánù 2

1 Jòhánù 2:23-28