1 Jòhánù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni èké? Ẹni tí ó sẹ́ pé Jésù kì í ṣe Kírísítì. Eléyìí ni Aṣòdìsí-Kírísítì: ẹni tí ó sẹ́ Baba àti Ọmọ.

1 Jòhánù 2

1 Jòhánù 2:18-29