1 Jòhánù 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ti ọ̀dọ̀ wá jáde, ṣùgbọ́n wọn kì í ṣe ara wa. Nítorí bí wọ́n bá jẹ́ ara wa, wọn ìbá bá wa dúró: ṣùgbọ́n jíjáde lọ wọn fihàn pé gbogbo wọn kì í ṣe ara wa.

1 Jòhánù 2

1 Jòhánù 2:15-23