1 Jòhánù 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwa bá wí pé àwa kò ní ẹ̀ṣẹ̀, àwa ń tan ara wa jẹ, òtítọ́ kò sì sí nínú wa.

1 Jòhánù 1

1 Jòhánù 1:5-9