1 Jòhánù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwa bá wí pé àwa ní ìdàpọ̀ pẹ̀lú rẹ̀, tí àwa sì ń rìn nínú òkùnkùn, àwa ń ṣèké, àwa kò sì gbé nínú òtítọ́.

1 Jòhánù 1

1 Jòhánù 1:1-10