1 Jòhánù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyè náà sì ti farahàn, àwa sì ti rí i, àwa sì ń jẹ́rí, àwa sì ń sọ ti ìyè àìnípẹ̀kun náà fún yín, tí ó ti ń bẹ lọ́dọ̀ Baba, tí ó sì farahàn fún wa.

1 Jòhánù 1

1 Jòhánù 1:1-10