1 Jòhánù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwa bá wí pé àwa kò dẹ́sẹ̀, àwa mú un ní èké, ọ̀rọ̀ rẹ̀ kò sì sí nínú wa.

1 Jòhánù 1

1 Jòhánù 1:4-10